Download another hot clean mp3 audio song by 9ice and this amazing music is titled “Arami”.
The new record is titled “Arami” and it produced by Carpenter.
Adigun Alapomeji brings back his melodious sound on this smashing jam “Arami” which means ‘My Body’. As Mixed & Mastered by OluMix you will surely Love this tune. 9ice has more songs in stock for his fans.
Listen up below!.
DOWNLOAD
Lyrics
Mi lẹ… mi lẹ
Òní lẹ’… Mi lẹ’
Kudira ti ba ni oya, ko bami gbe, gbe
Eruu ni ile aiye yii, o ni ohun tí mo fe fi se
You gat to let it vibrate, let it vibrate for me
Gbe su’mo mi, Ara ki sa f’ ara oooo
O yẹ kó ye Ẹ
Arami ń bẹ lọ’nà yeeeeh
Arami ń bẹ lọ’nà eeh
Arami ń bẹ lọ’nà yeeeeh
Arami ń bẹ lọ’nà eeh
Ara mi ń bẹ lọ’nà my dear ooh
Arami ń bẹ lọ’nà eeh
Arami ń bẹ lọ’nà Kudira
Arami mi ń bẹ lọ’nà yeeeh
Hmm hmm hmm
Jẹ’ kí n gbó ṣe rẹ kì mama ó tó dé ooo
I go take it easy on you jọ’wọ’ máa pariwo
Adigun ńlá ńlá
Adigun baálé ooo
Torí mo dangajia
Ẹ ti mo mi ládùúgbò èéh oo
You gat to let it vibrate, let it vibrate for me
Gbe su’mo mi, Ara ki sa f’ ara oooo
O yẹ kó ye Ẹ
Arami ń bẹ lọ’nà yeeeeh
Arami ń bẹ lọ’nà eeh
Arami ń bẹ lọ’nà yeeeeh
Arami ń bẹ lọ’nà eeh
Ara mi ń bẹ lọ’nà my dear ooh
Arami ń bẹ lọ’nà Kudira
Arami mi ń bẹ lọ’nà yeeeh
Jẹ ń gbọ’ ṣe yẹn
Jẹ’ ń bá ìṣe yẹn
Ọmọ gbọ’ ṣe yẹn
Jẹ’ bá ìṣe yẹn
Ọmọ jẹ ń lé ìṣe yẹn
Ọmọ jẹ ń lé ìṣe yẹn
Kí n lè wọ ‘bi ‘ṣe yẹn
Jẹ’ ń bá ìṣe yẹn
Ọmọ gbọ’ ṣe yẹn
Jẹ’ bá ìṣe yẹn
Ọmọ jẹ ń lé ìṣe yẹn
Ọmọ jẹ ń lé ìṣe yẹn
Kí n lè wọ ‘bi ‘ṣe yẹn
Yeeeeh eeeeeh
O le tún gbobe eeeeh
Fún wo bí dééeee èéh
Yeeeh yeeh ooh ooh
Arami ń bẹ lọ’nà yeeeeh
Arami… Arami
Arami ń bẹ lọ’nà eeh
Arami ń bẹ lọ’nà yeeeeh
Arami ń bẹ lọ’nà eeh
Ara mi ń bẹ lọ’nà my dear ooh
Arami ń bẹ lọ’nà Kudira
Arami mi ń bẹ lọ’nà yeeeh
Arami ń bẹ lọ’nà eeeh
Arami ń bẹ lọ’nà eeeh
Eeeh
Olumix
Yeeeh èéh Arami ń bẹ lọ’nà eeh