Download another hot new mp3 free audio song by Debra Crown-Olu and this amazing song is titled “Korin Si Oluwa ft Laolu Gbenjo “.
Listen and download below.
Debra Crown-Olu – Korin Si Oluwa ft Laolu Gbenjo DOWNLOAD
LYRICS
CHORUS:
Emi o kọrin si OLUWA, nitoriti o pọ̀ li ogo:
ẹṣin ati ẹlẹṣin on li o bì ṣubu sinu okun pupa.
Oluwa li agbara ati orin mi,
on li o si di ìgbala mi:
eyi li Ọlọrun mi, emi o si fi ìyin fun u;
Kabioyesi mo se iba re
Emi o kọrin si OLUWA,
CHORUS:
Emi o kọrin si OLUWA, nitoriti o pọ̀ li ogo:
ẹṣin ati ẹlẹṣin on li o bì ṣubu sinu okun pupa.
Oluwa, li asà fun mi; ogo mi;
olugbe ori mi soke.
Emi fi ohùn mi kigbe si Oluwa,
o si gbohùn mi lati òke mimọ́ rẹ̀ wá.
Emi o kọrin si OLUWA,
Oba to ‘n be ninu orun
Response: gbega mi o le sai gbega titi lai.
O ran omo ni se fayati
Response: gbega mi o le sai gbega titi lai.
You are bigger than the biggest
Response: Olowogbogboro ti ‘n gba omo re lofin
Response: A se kabiesi re eladumare tewogbope
INTERLUDE
(Omo egbala gbo in so ke).
Oba to ti wa o, k’ aye to wa
ti si tun ma wa nigba ti aye ko no si mo
Mo ni, Oluwa n’ be bi ti ati Jo
Response: A wa la o sin baba bi ta ti jo.
BRIDGE:
Ologun li OLUWA; OLUWA li orukọ rẹ̀.
ọwọ́ ọtún rẹ li ogo ninu agbara:
ọwọ́ ọtún rẹ fọ́ ọtá tútu.
Emi o kọrin si OLUWA,
Mo korin hallelujah
Mo ke hallelujah
Ona to di ti la o
Oluwa la ona ni bi to ko so na
Ona to di ti la o
Ogo oluwa won la ye mi