Download another hot new mp3 free audio song by Elizavocat and this amazing song is titled ” Oruko Re”.
Listen and download below.
Elizavocat – Oruko Re DOWNLOAD
LYRICS
Oh oh /2*
Oruko re
Your name is more than Jazz
Oruko re jogunlo /2*
Je koruko re lana, ko lana fun mi ooo
Jekorukore lana ko Lana fun mi o
Jesu, iwo logun mi o oo
Ogun ajisa
ogun ajipe
ogun ajiyin
ogun ajibo
mope o loni ki n rowo
kire wamiri
kaye fohungbogbo toje re wamiri
Ogun ti o l’overdose
ogun ti oni prescription
ogun ti ole baje lailai
ogun ti ole womi
ogun ti ole sunko
CHORUS:
Je koruko re lana, ko lana fun mi ooo
Jekorukore lana kolana fun mi o
Seborukore sa nigbekele mi
Jesu,
iwo logun tose gbarale,
ogun ti ole dissapoint
ogun to ngbe ogun mi
ogun to bori ogun
ogun to bori epe
ogun to n woni san lorukore
ogun to n tunisile
ogun to n yoni ninu ofin
ogun to n renilekun
ogun to n ti ni leyin ogun to n pani lerin
ogun to n yaye e ni pada si rere
ogun to n saye eni dotun
ogun to n yi itan aye eni pada
ogun to n sogun dogo
ogun to n sofo dogo
Call: Oluwa
Resp: Je koruko re lana, ko lana fun mi ooo
Jekorukore lana kolana fun mi o
Your name,
Oruko re to san bi ara, oruko re to jabi iji, oruko re lo nu omije nu, oruko re lo n taye eni se,
Oruko tokunrin npe, tobinrin npe
Tomode npe, Tagba npe, tagba npe to de n je lojojumo
Oruko to n dani nide, oruko to n wonisan, oruko to n lana fun ni, oruko to fun ni ni ireti, oruko toje jewe ategbo lo.
CHORUS:
Je koruko re lana, ko lana fun mi ooo
Jekorukore lana kolana fun mi o
Ogun to nje /2*
Oruko Jesu ohun nikan logun to n je
Ogun ti ole expire lailai, ogun to nje, oruko Jesu nikan logun to nje
Ogun ti ole yeye eni, ogun ti oni expire lailai, oruko Jesu nikan logun to n je