Adeoye Otemuyiwa-Adanimagbagbe – Maritemise

Adeoye Otemuyiwa-Adanimagbagbe – Maritemise

Download another hot new mp3 free audio song by Adeoye Otemuyiwa-Adanimagbagbe and this amazing song is titled ” Maritemise”.

Listen and download below.

Adeoye Otemuyiwa-Adanimagbagbe – Maritemise DOWNLOAD

LYRICS:

INTRO:

CHORUS: Bo ti wu ki ilu le to Maritemise o

BACKUP: Repeat Chorus/3×

(Adlip)

Lead repeat call: Bo ti wu ki ilu le to maritemise

Backup: Repeat Chorus

Lead Vocal: Ire owo ire Omo, aiku bale Oro

Backup: Repeat chorus

L/v: Bo ti wu ki naija le to maritemise Baba Backup repeat chorus

L/v: Oluwa nbe leyin mi o

Jehovah nbe leyin mi o

Adanimagbagbe nbe leyin mi o

Jehovah nbe leyin mi, Ajinde ati iye

O’nbe leyin mi, Bo ti ki ilu le to

Maritemise ooo

Backup: Repeat chorus

L/V: Ninu Odun yi ire gbogbo ko wo le mi ri o

Backup: Repeat Chorus

Lead: ilu le ile Cole maritemise o….Backup: Repeat Chorus

Syncopation (instrumental)

Backups: Maritemise /2× Bo ti le wu kilu le to Maritemise//2×

L/v: Ahh! Majemu re ni mo diro mo ileri re ni mo gbekele ooo/2× Eni gbekele loluwa ko ni jogun ofo, bo ti wu kilu leto Maritemise oo

Backups: Repaeat Chorus

L/v: Repeat Chorus

Backup: Repeat Chorus

Call: Ni nàijiria ni Oke okun Maritemise oo odidaadan — Backup: Repeat chorus

L/v: Bo ti wu ki ilu leto Maritemise

ADLIP: (Marona gbegba laye)

BRIDGE:

L/v: Ma fowo gbeyin leyin mi o/2×

Owo,se koko kosemani//2×

Bo ti wu ki ilu le to Maritemise ooo—-All: Repeat Chorus

L/V: ire gbogbo ko wo ile mi wa

Ki n’lowo lowo ki nribatise Baba oo

BACKUP: Repeat chorus

BRIDGE:

LEAD: Iyanu asele

BACKUPS: Odamiloju

Iyanu t’oju ari…. ” ”

Iyanu t’eti agbo.. ” ”

Iyanu t’enu aso..” ”

Asele n’ile mi ….” ”

Asele nile gbogbo wa….” ”

Iyanu ko wa mi ri …….” ”

Iyanu asele eee