Sola Allyson – Wa Wole

Sola Allyson – Alujanjankijan Ft Adekunle Gold

Download another hot new mp3 free audio song by Sola Allyson and this amazing song is titled “Wa Wole”

taken from her 2018 album  Imuse!

Listen up below.

Sola Allyson – Wa Wole DOWNLOAD

 

LYRICS

 

Verse 1
Eni o mobi ti mo ti n bo
Ko le dami lejo ibi mo de duro
Eni o mobi mo la koja
Ko le ro mi lejo ibi mo nre lowo, lowo
Oluwa lo mo’bi mo nre
Lo fi mumi labi mo la koja

Chorus
Mo dupe ooo
Mo yege
Imole tan sona mi
Moti bo oo
Moti bo oo
Moti bo

Wa wole ooo
Maa bo omo
Ona imole yi npeni
Wa je ninu aadun yen oo (nigba meji)

Verse 2
Eni o ba gbe’nu okunkun
Kole mo riri imole rara
Eni ebi opa ri
Kole more riri ipese ounje
Eni o ba jiya
Kole mo riri ohun ara nje

Repeat chorus /2x

Verse 3
Ibi mode
Oluwa lo se
Oro aye mi to ku
Mo fi le lowo
Ohun oju mi ri
O je nmo p’alanu loluwa

Ema lemi lere
Eni lani solododo
Ma de ‘bi maa de oo
Ona mi atubo la peregede

E o le dami duro
Eni mumi de ‘bi alagbara ni
Ma de ‘bi maa de oo
Ona mi atubo la peregede

Verse 4
Eyi to se koko nibe
Nipe kaa tona imole laye n’bi
Eni waye lai m’olu, lai mo ‘mole
Inu okukun ayeraye lo ngbe
Emi npinu lati rina imole
Aanu yami ya’ya lona mi

Repeat chorus /2x

Outro
Iri aanu ase, o ngbeni ga
Imole a tan, O dun gan
Isegun awa, O ngbeni ga
Imuse awa, o dun gan
Ibukun ase, O ngbeni ga
Ona imole yi npeni
Wa je ninu aadun yen oo