Tabernacle Mass Choir – Igbagbo Mi Duro Lori

Tabernacle Mass Choir – Igbagbo Mi Duro Lori

Download another hot new mp3 free audio song by Tabernacle Mass Choir and this amazing song is titled “Igbagbo Mi Duro Lori”.

Listen and download below.

Tabernacle Mass Choir – Igbagbo Mi Duro Lori DOWNLOAD

LYRICS

Igbagbo mi duro, l’ori

Eje at’ ododo Jesu;

Nko je gbekele ohun kan,

Lehin oruko nla Jesu:

Mo duro le Krist’ Apata,

Ile miran, iyanrin ni.

 

B’ ire-ije mi tile gun,

Or’-ofe Re ko yipada;

B’ o ti wu k’ iji na le to

Idakoro ni ko ni ye

 

Mo duro le Krist’ Apata,

Ile miran, iyanrin ni.

 

Majemu ati eje Re,

L’ em’ o romo b’ ikunmi de

Gbati ko s’atilehin mo

O je ireti nla fun mi:

Mo duro le Krist’ Apata

Ile miran, iyanrin ni.

 

Gbat’ ipe kehin ba si dun,

A! mba le wa ninu Jesu,

Ki nwo ododo Re nikan,

Ki nduro niwaju ite:

Mo duro le Krist’ Apata

Ile miran, iyanrin ni