Tope Alabi – Orun Oun Aye

Tope Alabi – Omo Ranti

Download another hot new mp3 free audio song by Tope Alabi and this amazing song is titled “Orun Oun Aye”

Gospel Artiste Tope Alabi Released a New EP Titled “Agbelebu”, Which Consists Of 6 Powerful Songs That Will Uplift Your Spirit And Surely Be Worth A Place On Your Playlist.

Listen and download below.

Tope Alabi – Orun Oun Aye DOWNLOAD

 

LYRICS

 

Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo n kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo n kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Didara orun, o n so togo Re o Olorun
Ewa Re to yi aye ka, n so togo Re o bo ti po to

Gbogbo eda, eranko at’ewebe n yin O o
Ise owo Re gbogbo loke nile, won n yin O o Baba
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Ola lo wo laso, ogo lo fi pa kaja orun
Ipa ese Re, o n han l’ori apata
Esin Re n fogo yan, l’ori awon okun o Olola nla

Kini yo waa se mi, ti n o j’okele yo, ti n o ni le juba Re Oba
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Gbogbo eemi inu mi, o n yin O yato o, Olorun mi
Iwo to mu mi la ina koja, to fi mumi goke, kini mba fi fun O
Kini mo to si ninu oore ofe ti mo ri gba lodo Re
O ba aye mi da majemu lati ‘nu ole

Oro Re ye, o si se
Oba ti ki i dale oro Re
Iwariri ni n o ma fi juba Re o
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e