Download another hot new mp3 free audio song by Temiloluwa and this amazing song is titled “My Prayer”.
Listen and download below.
Temiloluwa – My Prayer DOWNLOAD
LYRICS
Eledumare moti duro lenu ona mogboju mi soke gege bi omo ileri ti o fise wase temi Funmi
CHORUS
Eledumare se se
Eledumare se se
Eledumare se temifunmi 2x
Iwo nikan lo le soromidayo eledumare se temifunmi 2x
VERSE 1
Bi iranlowo eda badopin talole gbami ooo, Iwo mo sa towa oluwa wa ran mi lowo
Mogbeke mi Le oo baba setemifunmi
Mogbeke mi le oo olorun gbo adura miii
CHORUS
Eledumare se se
Eledumare se se
Eledumare se temifunmi 2x
Iwo nikan lo le soromidayo eledumare se temifunmi 2x
VERSE 2
Mo mope o lo lese jahovah,kosi ohun ti Iwo kole se
Oku lasaru ojo keta oti ra,oti ru sugbon sibe ojidid, Awon Ise iyanu to tise talole kawan tan Setemifunmi
Gege bi omo ileri timo je
Wa se temifunmi
CHORUS
Eledumare se se
Eledumare se se
Eledumare se temifunmi 2x
Iwo nikan lo le soromidayo eledumare se temifunmi 2x
Bi ireti badopin ti kosi oluranlowo Iwo nikan lo le se
Bi ireti badopin,afi Iwo afi Iwo nikan lo le bamiseeeeeeee